Ènìyàn tí kò ba ni rẹ́ a máa lépa ìmọ̀ ara rẹ̀;
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 18장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
Aláìgbọ́n kò rí inú dídùn sí òye
Nígbà ti ènìyàn búburú dé ni ẹ̀gàn dé,
Ọ̀rọ̀ ẹnu ènìyàn jẹ́ omi jíjìn,
Kò dára kí ènìyàn ṣe ojúsàájú fún ènìyàn búburú
Ètè aláìgbọ́n dá ìjà sílẹ̀
Ẹnu aláìgbọ́n ni ó ba tirẹ̀ jẹ́,
Ọ̀rọ̀ olófòófó dàbí oúnjẹ àdídùn;
Ẹni tí kò ṣe déédé nínú iṣẹ́ rẹ̀
Orúkọ Olúwa, ilé ìṣọ́ agbára ni;
Ọ̀rọ̀ olówó ni ìlú olódi wọn;
Ṣáájú ìṣubú ọkàn ènìyàn a kọ́kọ́ máa gbéraga,
Ẹni tí ó ń fèsì kí ó tó gbọ́,
Ọkàn ènìyàn a máa gbé e ró nígbà àìsàn,
Ọkàn olóye ní i gba ìmọ̀;
Ẹ̀bùn máa ń ṣí ọ̀nà fún ẹni tí ń fún ni lẹ́bùn
Ẹni tí ó kọ́kọ́ rọjọ́ máa ń dàbí i pé ó jàre,
Ìbò dídì máa ń parí ìjà
Arákùnrin tí a ṣẹ̀ sí ṣòro yípadà ju ìlú olódi lọ,
Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ikùn ènìyàn a yó;
Ikú àti ìyè ń bẹ nípa ahọ́n wọn,
Ẹni tí ó rí aya fẹ́, rí ohun rere,
Tálákà ń bẹ̀bẹ̀ fún àánú,
Ènìyàn tí ó ní ọ̀rẹ́ púpọ̀ le è parun,