Ǹjẹ́ ọgbọ́n kò ha ń kígbe síta?
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 8장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
Ní ibi gíga ní ẹ̀gbẹ́ ọ̀nà,
ní ẹgbẹ́ ibodè tí ó wọ ìlú,
“Sí i yín ẹ̀yin ènìyàn, ní mo ń kígbe pè;
Ẹ̀yin aláìmọ̀kan, ẹ kọ́gbọ́n;
Ẹ gbọ́, nítorí tí èmi ó sọ̀rọ̀ ohun iyebíye;
ẹnu mi ń sọ ohun tí í ṣe òtítọ́,
Gbogbo ọ̀rọ̀ ẹnu mi ni ó tọ́,
Fún olóye gbogbo rẹ̀ ni ó tọ̀nà;
Yan ẹ̀kọ́ mi dípò fàdákà,
nítorí ọgbọ́n ṣe iyebíye jù iyùn lọ,
“Èmi, ọgbọ́n ń gbé pẹ̀lú òye;
Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìkórìíra ibi
Ìmọ̀ràn àti ọgbọ́n tí ó yè kooro jẹ́ tèmi
Nípasẹ̀ mi ni ọba ń ṣàkóso
Nípasẹ̀ mi àwọn ọmọ-aládé ń ṣàkóso,
Mo fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn mi,
Lọ́dọ̀ mi ni ọrọ̀ àti ọlá wà,
Èso mi dára ju wúrà dáradára lọ;
Mò ń rìn ní ọ̀nà òdodo,
mò ń fi ọrọ̀ fún gbogbo àwọn tí ó fẹ́ràn mi
“Èmi ni Olúwa kọ́kọ́ dá nínú iṣẹ́ rẹ̀.
a ti yàn mí láti ayérayé,
Nígbà tí kò tí ì sí Òkun, ni a ti bí mi,
kí a tó fi àwọn òkè sí ipò wọn,
kí ó tó dá ilẹ̀ ayé tàbí àwọn oko rẹ̀
Mo wà níbẹ̀ nígbà tí ó fi àwọn ọ̀run sí ipò wọn,
nígbà tí ó ṣẹ̀dá òfúrufú lókè
nígbà tí ó ṣe ààlà fún omi Òkun
Nígbà náà èmi ni gbẹ́nàgbẹ́nà ẹ̀gbẹ́ rẹ̀
Mo ń yọ̀ nínú gbogbo àgbáyé tí ó dá
“Nítorí náà báyìí, ẹ̀yin ọmọ mi,
Fetí sí ìtọ́sọ́nà mi kí o sì gbọ́n;
Ìbùkún ni fún ẹni tí ó fetísílẹ̀ sí mi,
Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá rí mi rí ìyè
Ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ̀ láti rí ń pa ara rẹ̀ lára