Ọmọ mi, fiyèsí ọgbọ́n mi,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 5장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
kí ìwọ sì lè ní ìṣọ́ra
Nítorí ètè àwọn àjèjì obìnrin a máa sun bi oyin,
Ṣùgbọ́n ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín, ó korò ju òróǹró lọ,
Ẹsẹ̀ rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí ọ̀nà ikú
Kí ìwọ má ba à já ipa ọ̀nà ìyè;
Nítorí náà, ẹ̀yin ọmọ mi, ẹ dẹtí sí mi,
Rìn ní ọ̀nà tí ó jìnnà sí ti rẹ̀,
àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ yóò gbé gbogbo ọlá rẹ lé ẹlòmíràn lọ́wọ́
Kí a má ba à fi ọrọ̀ rẹ fún àjèjì ènìyàn,
Ní ìgbẹ̀yìn ayé rẹ ìwọ yóò kérora,
Ìwọ yóò wí pé, “Mo ti kórìíra ẹ̀kọ́ tó!
N kò gbọ́rọ̀ sí àwọn olùkọ́ mi lẹ́nu,
Mo ti bẹ̀rẹ̀ ìparun pátápátá
Mu omi láti inú kànga tìrẹ,
Ó ha yẹ kí omi ìsun rẹ kún àkúnya sí ojú ọ̀nà
Jẹ́ kí wọn jẹ́ tìrẹ nìkan,
Jẹ́ kí orísun rẹ kí ó ní ìbùkún;
Abo àgbọ̀nrín tó dára, ìgalà tí ó wu ni jọjọ,
Ọmọ mi, èéṣe tí ìwọ ó fi máa yọ̀ nínú ìfẹ́ obìnrin panṣágà,
Nítorí ọ̀nà ènìyàn kò fi ara sin rárá fún Olúwa
Ìwà búburú ènìyàn búburú ni yóò mú kó bọ́ sínú okùn;
Yóò kú ní àìgba ẹ̀kọ́