Ọgbọ́n ti kọ́ ilé rẹ̀,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 9장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
ó ti fi ilé pọn tí, ó ti fọ̀nà rokà.
ó ti rán àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ jáde, ó sì ń pè,
“Jẹ́ kí gbogbo àwọn aláìgbọ́n wọ ibí wá!”
“Wá, ẹ wá jẹ́ oúnjẹ mi
Fi ìwà àìmọ̀kan rẹ sílẹ̀ ìwọ yóò sì yè;
“Ẹnikẹ́ni tí ó bá bá ẹlẹ́gàn wí, kọ lẹ́tà sí àbùkù
Má ṣe bá ẹlẹ́gàn wí, àìṣe bẹ́ẹ̀ yóò kórìíra rẹ.
kọ́ ọlọ́gbọ́n ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́, yóò sì gbọ́n sí i
“Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n,
Nítorí nípasẹ̀ mi ọjọ́ rẹ yóò gùn
Bí ìwọ bá gbọ́n, ọgbọ́n rẹ yóò fún ọ ní èrè:
Òmùgọ̀ obìnrin jẹ́ aláriwo;
Ó jókòó ní ẹnu-ọ̀nà ilé rẹ̀
ó ń pe àwọn tí ó ń kọjá lọ,
“Jẹ́ kí gbogbo ẹni tí ó jẹ́ aláìlóye súnmọ́ bí!”
“Omi tí a jí mu dùn
Ṣùgbọ́n wọn ò funra pé àwọn òkú wà níbẹ̀,