Ọmọ mi, bí ìwọ bá gba ọ̀rọ̀ mi,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 2장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
tí ìwọ dẹtí rẹ sílẹ̀ sí ọgbọ́n
àní, bí ìwọ bá ké tọ ìmọ̀ lẹ́yìn,
bí ìwọ bá ṣàfẹ́rí rẹ̀ bí i fàdákà
Nígbà náà ni ìwọ yóò bẹ̀rù Olúwa,
Nítorí Olúwa ni ó ń fún ni ní ọgbọ́n,
Ó to ìgbàlà fún àwọn olódodo,
Ó pa ipa ọ̀nà ìdájọ́ mọ́
Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ òdodo àti ìdájọ́,
Nítorí ọgbọ́n yóò wọ inú ọkàn rẹ
Ìmòye yóò pa ọ mọ́
Ọgbọ́n yóò gbà ọ́ là kúrò ní ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú,
ẹni tí ó kúrò ní ọ̀nà ìdúró ṣinṣin
ẹni tí ó yọ̀ nínú ṣíṣe búburú,
ọ̀nà ẹni tí ó wọ́
Yóò gba ìwọ pẹ̀lú là kúrò lọ́wọ́ àwọn àjèjì obìnrin,
ẹni tí ó ti kọ ọkọ àkọ́fẹ́ ìgbà èwe rẹ̀ sílẹ̀
Nítorí ilé rẹ̀ jẹ́ ọ̀nà sí ikú
Kò sẹ́ni tó lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ tí ó padà
Bẹ́ẹ̀ ni ìwọ yóò rìn ní ọ̀nà àwọn ènìyàn rere
Nítorí ẹni dídúró ṣinṣin yóò gbé ní ilé náà
Ṣùgbọ́n a ó ké ènìyàn búburú kúrò lórí ilẹ̀ náà