Yíyan orúkọ rere sàn ju púpọ̀ ọrọ̀ lọ,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 22장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
Ọlọ́rọ̀ àti tálákà péjọpọ̀:
Ọlọ́gbọ́n ènìyàn ti rí ibi tẹ́lẹ̀,
Èrè ìrẹ̀lẹ̀ àti ìbẹ̀rù Olúwa ni ọrọ̀ ọlá, àti ìyè.
Ègún àti ìdẹ̀kùn ń bẹ ní ọ̀nà aláyídáyidà:
Tọ́ ọmọdé ní ọ̀nà tí yóò tọ̀:
Ọlọ́rọ̀ ṣe olórí olùpọ́njú,
Ẹni tí ó bá fúnrúgbìn ẹ̀ṣẹ̀, yóò ká asán:
Ẹni tí ó ní ojú àánú ni a ó bùkún fún;
Lé ẹlẹ́gàn sí ìta, ìjà yóò sì jáde;
Ẹni tí ó fẹ́ ìwà funfun ti àyà,
Ojú Olúwa pa ìmọ̀ mọ́,
Ọ̀lẹ wí pé, “Kìnnìún ń bẹ lóde!
Ẹnu àwọn àjèjì obìnrin, ihò jíjìn ni;
Àyà ọmọdé ni ìwà wèrè dì sí;
Ẹni tó ń ni tálákà lára láti ní ọrọ̀,
Dẹtí rẹ sílẹ̀,
Nítorí ohun dídùn ni bí ìwọ bá pa wọ́n mọ́ ní inú rẹ;
Kí ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ lè wà ní ti Olúwa,
Èmi kò ha ti kọ̀wé ohun dáradára
kí ó lè mú ọ mọ ìdájú ọ̀rọ̀ òtítọ́;
Má ṣe ja tálákà ní olè, nítorí tí ó jẹ́ tálákà:
nítorí Olúwa yóò gbèjà wọn,
Má ṣe bá oníbìínú ènìyàn ṣe ọ̀rẹ́;
Kí ìwọ má ba à kọ́ ìwà rẹ̀, ìwọ a sì gba ìkẹ́kùn fún ara rẹ.
Má ṣe wà nínú àwọn tí ń ṣe ìgbọ̀nwọ́,
Bí ìwọ kò bá ní nǹkan tí ìwọ ó fi san,
Má ṣe yẹ ààlà ilẹ̀ ìgbàanì,
Ìwọ ha rí ènìyàn tí ó ń fi àìṣe ìmẹ́lẹ́ ṣe iṣẹ́ rẹ̀?