Àwọn ọ̀rọ̀-ìjìnlẹ̀ ti Lemueli ọba, ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ tí ìyá rẹ̀ kọ́ ọ,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 31장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
“Gbọ́ ìwọ ọmọ mi, gbọ́ ìwọ ọmọ inú mi!
Má ṣe lo agbára rẹ lórí obìnrin,
“Kì í ṣe fún àwọn ọba, ìwọ Lemueli,
kí wọn má ba à mu ọtí yó kí wọn sì gbàgbé ohun tí òfin wí,
Fi ọtí líle fún àwọn tí ń ṣègbé
Jẹ́ kí wọn mu ọtí kí wọn sì gbàgbé òsì wọn
“Sọ̀rọ̀ lórúkọ àwọn tí kò le sọ̀rọ̀ fúnra wọn
Sọ̀rọ̀ kí o sì ṣe ìdájọ́ àìṣègbè
Ta ni ó le rí aya oníwà rere?
Ọkọ rẹ̀ ní ìgbẹ́kẹ̀lé púpọ̀ nínú rẹ̀
Ire ní ó ń ṣe fún un, kì í ṣe ibi
Ó sa aṣọ irun àgùntàn olówùú àti ọ̀gbọ̀
Ó dàbí ọkọ̀ ojú omi tí àwọn oníṣòwò;
Ó dìde nígbà tí òkùnkùn sì kùn;
Ó kíyèsi oko kan, ó sì rà á;
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ tagbára tagbára
Ó rí i pé òwò òun pé
Ní ọwọ́ rẹ̀, ó di kẹ̀kẹ́ òwú mú
O la ọwọ́ rẹ̀ sí àwọn tálákà
Nígbà tí òjò-dídì rọ̀, kò bẹ̀rù nítorí ìdílé rẹ̀
Ó ṣe aṣọ títẹ́ fún ibùsùn rẹ̀;
A bọ̀wọ̀ fún ọkọ rẹ̀ ní ẹnu ibodè ìlú
Ó ń ṣe àwọn aṣọ dáradára ó sì ń tà wọ́n
Agbára àti ọlá ni ó wò ọ́ láṣọ
A sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ọgbọ́n
Ó ń bojútó gbogbo ètò ilé rẹ̀
Àwọn ọmọ rẹ̀ dìde wọ́n sì pè é ní alábùkún
“Ọ̀pọ̀lọpọ̀ obìnrin ní ń ṣe nǹkan ọlọ́lá
Ojú dáradára a máa tan ni, ẹwà sì jẹ́ asán
Sì fún un ní èrè tí ó tọ́ sí i