Ọmọ mi, má ṣe gbàgbé ẹ̀kọ́ mi.
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 3장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
Nítorí ọjọ́ gígùn, ẹ̀mí gígùn, àti àlàáfíà,
Má ṣe jẹ́ kí ìfẹ́ àti òtítọ́ ṣíṣe fi ọ́ sílẹ̀ láéláé
Nígbà náà ni ìwọ yóò rí ojúrere àti orúkọ rere
Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ
Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ
Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ
Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ
Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún Olúwa,
nígbà náà ni àká rẹ yóò kún àkúnya
Ọmọ mi, má ṣe kẹ́gàn ìbáwí Olúwa
nítorí Olúwa a máa bá àwọn tí ó fẹ́ràn wí
Ìbùkún ni fún ẹni tí ó ní ìmọ̀,
nítorí ó ṣe èrè ju fàdákà lọ
Ó ṣe iyebíye ju iyùn lọ;
Ẹ̀mí gígùn ń bẹ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀;
Àwọn ọ̀nà rẹ jẹ́ ọ̀nà ìtura,
Igi ìyè ni ó jẹ́ fún gbogbo ẹni tí ó bá gbà á;
Nípa ọgbọ́n, Olúwa fi ìpìlẹ̀ ilẹ̀ ayé sọlẹ̀; nípa òye, ó fi àwọn ọ̀run sí ipò wọn;
nípa ìmọ̀ rẹ̀ ó pín ibú omi ní yà,
Ọmọ mi, pa ọgbọ́n tí ó yè kooro àti ìmòye mọ́,
Wọn yóò jẹ́ ìyè fún ọ,
Nígbà náà ni ìwọ yóò bá ọ̀nà rẹ lọ ní àìléwu,
Nígbà tí ìwọ bá dùbúlẹ̀, ìwọ kì yóò bẹ̀rù,
Má ṣe bẹ̀rù ìdààmú òjijì,
Nítorí Olúwa yóò jẹ́ ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ,
Má ṣe fa ọwọ́ ìre sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ àwọn tí ṣe tìrẹ,
Má ṣe wí fún aládùúgbò rẹ pé,
Má ṣe pète ohun búburú fún aládùúgbò rẹ,
Má ṣe fẹ̀sùn kan ènìyàn láìnídìí,
Má ṣe ṣe ìlara ènìyàn jàgídíjàgan
Nítorí Olúwa kórìíra ènìyàn aláyídáyidà
Ègún Olúwa ń bẹ lórí ilé ènìyàn búburú,
Ó fi àwọn ẹlẹ́yà ṣe yẹ̀yẹ́,
Ọlọ́gbọ́n jogún iyì,