Ọkàn ọba ń bẹ lọ́wọ́ Olúwa;
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 21장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
Gbogbo ọ̀nà ènìyàn dàbí i pé ó dára lójú rẹ̀,
Ṣíṣe ohun tí ó dára tí ó sì tọ̀nà
Ojú tí ó gbéga àti ọkàn ìgbéraga,
Ètè àwọn olóye jásí èrè
Ìṣúra tí a kójọ nípasẹ̀ ahọ́n tí ń parọ́
Ìwà ipá àwọn ènìyàn búburú yóò wọ́ wọn lọ,
Ọ̀nà ẹlẹ́ṣẹ̀ kún fún ìwà ẹ̀ṣẹ̀
Ó sàn láti máa gbé ní kọ̀rọ̀ orí òrùlé
Ènìyàn búburú ń fẹ́ ibi
Nígbà tí a bá ń fìyà jẹ ẹlẹ́gàn,
Olódodo ṣàkíyèsí ilé ènìyàn búburú
Ẹnikẹ́ni tí ó bá ti di etí rẹ̀ sí igbe olùpọ́njú,
Ọ̀rẹ́ ìkọ̀kọ̀, mú ìbínú kúrò:
Ayọ̀ ni fún olódodo láti ṣe ìdájọ́:
Ẹni tí ó bá yà kúrò ní ọ̀nà òye,
Ẹni tí ó bá fẹ́ afẹ́, yóò di tálákà:
Ènìyàn búburú ni yóò ṣe owó ìràpadà fún olódodo,
Ó sàn láti jókòó ní aginjù ju pẹ̀lú
Ìṣúra iyebíye àti òróró wà ní ibùgbé ọlọ́gbọ́n;
Ẹni tí ó bá tẹ̀lé òdodo àti àánú yóò rí ìyè,
Ọlọ́gbọ́n gòkè odi ìlú àwọn alágbára,
Ẹnikẹ́ni tí ó bá pa ẹnu àti ahọ́n rẹ̀ mọ́,
Agbéraga àti alágídí ènìyàn ń gan orúkọ ara rẹ̀ nítorí ó ń hùwà nínú ìwà ìgbéraga rẹ̀,
Ẹlẹ́rìí èké yóò ṣègbé, àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ yóò parun láé;
Ó ń fi ìlara ṣe ojúkòkòrò ní gbogbo ọjọ́:
Ẹbọ ènìyàn búburú, ìríra ni:
Ẹlẹ́rìí èké yóò ṣègbé:
Ènìyàn búburú mú ojú ara rẹ̀ le:
Kò sí ọgbọ́n, kò sí ìmòye,
A ń múra ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun: