Ọlọ́gbọ́n ọmọ gba ẹ̀kọ́ baba rẹ̀,
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 13장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ènìyàn ń gbádùn ohun rere,
Ẹnikẹ́ni tí ó ṣọ́ ẹnu rẹ̀ pa ẹnu ara rẹ̀ mọ́,
Ọkàn ọ̀lẹ ń fẹ́, ṣùgbọ́n kò rí nǹkan kan,
Olódodo kórìíra ohun tí í ṣe irọ́,
Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú,
Ènìyàn kan díbọ́n bí ẹni tí ó ní ọrọ̀ síbẹ̀ kò ní nǹkan kan
Ọrọ̀ ènìyàn le è ra ẹ̀mí rẹ̀
Ìmọ́lẹ̀ olódodo tàn roro,
Ìgbéraga máa ń dá ìjà sílẹ̀ ni
Owó tí a fi ọ̀nà èrú kójọ yóò ṣí lọ,
Ìrètí tí ń falẹ̀ máa ń mú kí ọkàn ṣàárẹ̀
Ẹni tí ó kẹ́gàn ẹ̀kọ́ yóò jìyà rẹ̀
Ìkọ́ni ọlọ́gbọ́n jẹ́ orísun ìyè,
Òye pípé ń mú ni rí ojúrere,
Gbogbo olóye ènìyàn máa ń hùwà pẹ̀lú ìmọ̀,
Ìránṣẹ́ búburú bọ́ sínú ìdààmú
Ẹni tí ó kọ ìbáwí yóò di tálákà yóò sì rí ìtìjú,
Ìfẹ́ tí a mú ṣẹ dùn mọ́ ọkàn
Ẹni tí ó ń bá ọlọ́gbọ́n rìn yóò gbọ́n
Òsì a máa ta ẹlẹ́ṣẹ̀,
Ènìyàn rere a máa fi ogún sílẹ̀ fún àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀,
Ilẹ̀ ẹ tálákà le è mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìre oko wá
Ẹni tí ó fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kórìíra ọmọ rẹ̀
Olódodo jẹ́wọ́ títí ó fi tẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùn