Òkèlè gbígbẹ tòun tàlàáfíà àti ìdákẹ́ jẹ́ẹ́ sàn
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 17장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
Ọlọ́gbọ́n ìránṣẹ́ yóò ṣàkóso adójútini ọmọ,
Iná ni a fi fọ́ fàdákà àti wúrà,
Ènìyàn búburú ń tẹ́tí sí ètè tí ń sọ ibi;
Ẹnikẹ́ni tí ó bá sín olùpọ́njú jẹ, ó gan Ẹlẹ́dàá rẹ̀,
Ọmọ ọmọ ni adé orí arúgbó,
Ọ̀rọ̀ dídùn kò yẹ aṣiwèrè,
Òkúta iyebíye jẹ́ ẹ̀bùn ní ojú ẹni tí ó ni í,
Ẹni tí ó fojú fo ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ ẹ́ mú kí ìfẹ́ gbòòrò sí i.
Ọ̀rọ̀ ìbáwí dun olóye ènìyàn
Orí kunkun ni ènìyàn ìkà máa ń ṣe,
Ó sàn kí ènìyàn pàdé beari tí a ti kó lọ́mọ
Bí ènìyàn kan bá fi ibi san ìre,
Bíbẹ̀rẹ̀ ìjà dàbí ẹni tí ó dá ojú fún adágún omi;
Gbígbé ẹ̀bi fún aláre àti dídá ẹni jàre lẹ́bi,
Kí ni ìwúlò owó lọ́wọ́ aṣiwèrè,
Ọ̀rẹ́ a máa fẹ́ni nígbà gbogbo,
Ènìyàn aláìgbọ́n ṣe ìbúra,
Ẹni tí ó fẹ́ràn ìjà fẹ́ràn ẹ̀ṣẹ̀;
Ènìyàn aláyídáyidà ọkàn kì í gbèrú,
Láti bí aláìgbọ́n lọ́mọ a máa fa ìbànújẹ́ ọkàn,
Ọkàn tí ó túká jẹ́ oògùn gidi,
Ènìyàn búburú a gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀
Olóye ènìyàn gbójú wo ọgbọ́n níwájú,
Aṣiwèrè ọmọ mú ìbànújẹ́ bá baba rẹ̀
Kò dára láti fìyà jẹ ènìyàn tí kò ṣẹ̀,
Ènìyàn tó ní ìmọ̀ máa ń ṣọ́ra fún àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ń sọ,
Kódà aláìgbọ́n máa ń dàbí ọlọ́gbọ́n bí ó bá dákẹ́,