Má ṣe yangàn nítorí ọ̀la
JA
Copywork
Yoruba OYCB Proverbs 27장
写経は速く終える入力練習ではなく、一節ずつみ言葉の文と流れを改めて受け止める時間です。入力内容はこのブラウザに一時保存され、ログインするとアカウントにも保存されます。
小見出し単位で進める · Proverbs
Jẹ́ kí ẹlòmíràn yìn ọ́ dípò ẹnu ara rẹ,
Òkúta wúwo, erùpẹ̀ sì wúwo
Ìbínú ni ìkà, ìrunú sì burú púpọ̀
Ìbániwí gbangba sàn
Òtítọ́ ni ọgbẹ́ ọ̀rẹ́,
Kódà oyin kò dùn lẹ́nu ẹni tí ó ti yó
Bí ẹyẹ tí ó ṣáko lọ kúrò níbi ìtẹ́ rẹ̀
Ìpara olóòórùn dídùn àti tùràrí ń mú ayọ̀ wá sínú ọkàn
Má ṣe kọ ọ̀rẹ́ rẹ àti ọ̀rẹ́ baba rẹ sílẹ̀,
Gbọ́n, ọmọ mi, kí o sì mú ayọ̀ wá sínú ọkàn mi
Ọlọ́gbọ́n rí ewu, ó sì fi ara pamọ́
Gba aṣọ ẹni tí ó ṣe onídùúró fún àjèjì
Bí ènìyàn kan ń kígbe súre fún aládùúgbò rẹ ní òwúrọ̀
Àyà tí ó máa ń jà dàbí
dídá a lẹ́kun dàbí ìgbà tí ènìyàn ń dá afẹ́fẹ́ lẹ́kun
Bí irin tí ń pọ́n irin mú
Ẹni tí ó tọ́jú igi ọ̀pọ̀tọ́ yóò jẹ èso rẹ̀
Bí omi tí ń ṣe àfihàn ojú, nígbà tí a bá wò ó
Kò tẹ́ ikú àti ìparun lọ́rùn rí
Iná fún fàdákà iná ìléru fún wúrà,
Bí a tilẹ̀ gún aláìgbọ́n nínú odó,
Rí i dájú pé o mọ ipò tí àwọn agbo àgùntàn rẹ wà
nítorí ọrọ̀ kì í pẹ́ lọ títí
Nígbà tí a bá kó koríko, ewéko tuntun yóò sì hù jáde, a ó sì kó koríko àwọn orí òkè wọlé
àwọn àgùntàn yóò pèsè aṣọ fún ọ,
Ìwọ yóò ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ wàrà ewúrẹ́